Mat 7:14
Mat 7:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori pe hihá ni ẹnu-ọ̀na na, ati toro li oju-ọ̀na na, ti o lọ si ibi ìye, diẹ li awọn ẹniti o nrin i.
Pín
Kà Mat 7Mat 7:14 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn ọ̀nà ìyè há, ẹnu ọ̀nà rẹ̀ sì fún. Díẹ̀ sì ni àwọn tí wọ́n rí i.
Pín
Kà Mat 7