Mat 7:1-2
Mat 7:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ máṣe dani li ẹjọ, ki a ma bà da nyin li ẹjọ. Nitori irú idajọ ti ẹnyin ba ṣe, on ni a o si ṣe fun nyin; irú òṣuwọn ti ẹnyin ba fi wọ̀n, on li a o si fi wọ̀n fun nyin.
Pín
Kà Mat 7Mat 7:1-2 Yoruba Bible (YCE)
“Ẹ má ṣe dá eniyan lẹ́jọ́, kí Ọlọrun má baà dá ẹ̀yin náà lẹ́jọ́. Nítorí irú ẹjọ́ tí ẹ bá dá eniyan ni Ọlọrun yóo dá ẹ̀yin náà. Irú ìwọ̀n tí ẹ bá lò fún eniyan ni Ọlọrun yóo lò fún ẹ̀yin náà.
Pín
Kà Mat 7