Mat 18:3
Mat 18:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si wipe, Lõtọ ni mo wi fun nyin, bikoṣepe ẹnyin ba pada, ki ẹ si dabi awọn ọmọ kekere, ẹnyin kì yio le wọle ijọba ọrun.
Pín
Kà Mat 18Mat 18:3 Yoruba Bible (YCE)
ó ní, “Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé, bí ẹ kò bá yipada kí ẹ dàbí àwọn ọmọde, ẹ kò ní wọ ìjọba ọ̀run.
Pín
Kà Mat 18