Mat 1:11-12
Mat 1:11-12 Yoruba Bible (YCE)
Josaya bí Jekonaya ati àwọn arakunrin rẹ̀ ní àkókò tí wọn kó àwọn ọmọ Israẹli lẹ́rú lọ sí Babiloni. Lẹ́yìn tí wọn kó wọn lẹ́rú lọ sí Babiloni, Jekonaya bí Ṣealitieli, Ṣealitieli bí Serubabeli.
Pín
Kà Mat 1Mat 1:11-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Josiah sì ni baba Jekoniah àti àwọn arákùnrin rẹ̀ ní àkókò ìkólọ sí Babeli. Lẹ́yìn ìkólọ sí Babeli: Jekoniah ni baba Ṣealitieli; Ṣealitieli ni baba Serubbabeli
Pín
Kà Mat 1Mat 1:11-12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Josiah si bí Jekoniah ati awọn arakunrin rẹ̀, nigba ikolọ si Babiloni. Lẹhin ikolọ si Babiloni ni Jekoniah bí Sealtieli; Sealtieli si bí Serubabeli
Pín
Kà Mat 1