Luk 3:10-11
Luk 3:10-11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Awọn enia si mbi i pe, Kini ki awa ki o ha ṣe? O dahùn o si wi fun wọn pe, Ẹniti o ba li ẹ̀wu meji, ki o fi ọkan fun ẹniti kò ni; ẹniti o ba si li onjẹ, ki o ṣe bẹ̃ pẹlu.
Pín
Kà Luk 3Awọn enia si mbi i pe, Kini ki awa ki o ha ṣe? O dahùn o si wi fun wọn pe, Ẹniti o ba li ẹ̀wu meji, ki o fi ọkan fun ẹniti kò ni; ẹniti o ba si li onjẹ, ki o ṣe bẹ̃ pẹlu.