Luk 24:6-7
Luk 24:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ko si nihinyi, ṣugbọn o jinde: ẹ ranti bi o ti wi fun nyin nigbati o wà ni Galili, Pe, A ko le ṣaima fi Ọmọ-enia le awọn enia ẹlẹsẹ lọwọ, a o si kàn a mọ agbelebu, ni ijọ kẹta yio si jinde.
Pín
Kà Luk 24Luk 24:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Luk 24