Luk 24:30
Luk 24:30 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si ṣe, bi o ti ba wọn joko tì onjẹ, o mu àkara, o sure si i, o si bù u, o si fifun wọn.
Pín
Kà Luk 24Luk 24:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ó sì ṣe, bí ó ti bá wọn jókòó ti oúnjẹ, ó mú àkàrà, ó súre sí i, ó sì bù ú, ó sì fi fún wọn.
Pín
Kà Luk 24Luk 24:30 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si ṣe, bi o ti ba wọn joko tì onjẹ, o mu àkara, o sure si i, o si bù u, o si fifun wọn.
Pín
Kà Luk 24