Luk 19:37-38
Luk 19:37-38 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi o si ti sunmọ eti ibẹ̀ ni gẹrẹgẹrẹ òke Olifi, gbogbo ijọ awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ bẹ̀rẹ si iyọ̀, ati si ifi ohùn rara yìn Ọlọrun, nitori iṣẹ nla gbogbo ti nwọn ti ri; Wipe, Olubukun li Ọba ti o mbọ̀ wá li orukọ Oluwa: alafia li ọrun, ati ogo loke ọrun.
Pín
Kà Luk 19Luk 19:37-38 Yoruba Bible (YCE)
Nígbà tí ó súnmọ́ gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè Olifi, ogunlọ́gọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí fi ayọ̀ kígbe sókè, wọ́n ń yin Ọlọrun nítorí gbogbo ohun ńlá tí wọ́n ti rí. Wọ́n ń wí pé, “Aláásìkí ni ẹni tí ó ń bọ̀ bí ọba ní orúkọ Oluwa. Alaafia ní ọ̀run! Ògo ní òkè ọ̀run!”
Pín
Kà Luk 19