Luk 12:40
Luk 12:40 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitorina ki ẹnyin ki o mura pẹlu: Nitori Ọmọ-enia mbọ̀ ni wakati ti ẹnyin kò daba.
Pín
Kà Luk 12Luk 12:40 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ̀yin náà, ẹ wà ní ìmúrasílẹ̀, nítorí ní àkókò tí ẹ kò nírètí ni Ọmọ-Eniyan yóo dé.”
Pín
Kà Luk 12