Mose si wipe, Eyi li ohun ti OLUWA filelẹ li aṣẹ, ki ẹnyin ki o ṣe: ogo OLUWA yio si farahàn nyin.
Mose sọ fún wọn pé, “Ohun tí OLUWA paláṣẹ fun yín láti ṣe nìyí, ògo OLUWA yóo hàn sí yín.”
Nígbà náà ni Mose wí pé, “Ohun tí OLúWA pàṣẹ fún yín láti ṣe nìyìí, kí ògo OLúWA bá à lè farahàn yín.”
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò