OLUWA bá rán iná kan jáde, iná náà jó wọn pa, wọ́n sì kú níwájú OLUWA.
Iná si ti ọdọ OLUWA jade, o si run wọn, nwọn si kú niwaju OLUWA.
Torí èyí iná jáde láti ọ̀dọ̀ OLúWA, ó sì jó wọn pa, wọ́n sì kú níwájú OLúWA.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò