Joṣ 16:10
Joṣ 16:10 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn wọn kò lé àwọn ará Kenaani tí ń gbé Geseri jáde, nítorí náà, àwọn ará Kenaani ń gbé ààrin ẹ̀yà Efuraimu títí di òní olónìí. Ẹ̀yà Efuraimu ń fi tipátipá mú wọn ṣiṣẹ́ bí ẹrú.
Pín
Kà Joṣ 16Joṣ 16:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Wọn kò lé àwọn ara Kenaani tí ń gbé ni Geseri kúrò, títí di òní yìí ni àwọn ará Kenaani ń gbé láàrín àwọn ènìyàn Efraimu, Ṣùgbọ́n wọ́n mú wọ́n sìn.
Pín
Kà Joṣ 16Joṣ 16:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nwọn kò si lé awọn ara Kenaani ti ngbé Geseri jade: ṣugbọn awọn ara Kenaani joko lãrin Efraimu titi di oni yi, nwọn si di ẹrú lati ma sìnru.
Pín
Kà Joṣ 16