Ṣugbọn kò si ẹniti o wipe, Nibo ni Ọlọrun Ẹlẹda mi wà, ti o fi orin fun mi li oru?
Ṣugbọn kò sí ẹni tí ó bèèrè pé, ‘Níbo ni Ọlọrun Ẹlẹ́dàá mi wà, tíí fún ni ní orin ayọ̀ lóru
Ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó wí pé, ‘Níbo ni Ọlọ́run Ẹlẹ́dàá mi wà tí ó sì fi orin fún mi ní òru
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò