Joh 21:21-22
Joh 21:21-22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbati Peteru ri i, o wi fun Jesu pe, Oluwa, Eleyi ha nkọ́? Jesu wi fun u pe, Bi emi ba fẹ ki o duro titi emi o fi de, kili eyini si ọ? Ìwọ mã tọ̀ mi lẹhin.
Pín
Kà Joh 21Nigbati Peteru ri i, o wi fun Jesu pe, Oluwa, Eleyi ha nkọ́? Jesu wi fun u pe, Bi emi ba fẹ ki o duro titi emi o fi de, kili eyini si ọ? Ìwọ mã tọ̀ mi lẹhin.