Emi ha iṣe Ọlọrun itosi? li Oluwa wi, kì iṣe Ọlọrun lati okere pẹlu?
“Ṣé nítòsí nìkan ni mo ti jẹ́ Ọlọrun ni, èmi kì í ṣe Ọlọrun ọ̀nà jíjìn?
“Ǹjẹ́ Ọlọ́run tòsí nìkan ni Èmi bí?” ni OLúWA wí, “kì í sì í ṣe Ọlọ́run ọ̀nà jíjìn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò