Isa 6:8
Isa 6:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi si gbọ́ ohùn Oluwa pẹlu wipe, Tali emi o rán, ati tani yio si lọ fun wa? Nigbana li emi wipe, Emi nĩ; rán mi.
Pín
Kà Isa 6Isa 6:8 Yoruba Bible (YCE)
Mo wá gbọ́ ohùn OLUWA ó ní, “Ta ni kí n rán? Ta ni yóo lọ fún wa?” Mo bá dáhùn, mo ní: “Èmi nìyí, rán mi.”
Pín
Kà Isa 6