Isa 59:19
Isa 59:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Láti ìwọ̀-oòrùn, àwọn ènìyàn yóò bẹ̀rù orúkọ OLúWA, àti láti ìlà-oòrùn, wọn yóò bọ̀wọ̀ fún ògo rẹ̀. Nítorí òun yóò wá gẹ́gẹ́ bí i rírú omi èyí tí èémí OLúWA ń tì lọ.
Pín
Kà Isa 59