Isa 55:2
Isa 55:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori kini ẹ ṣe nná owo fun eyiti kì iṣe onjẹ? ati lãla nyin fun eyi ti kì itẹnilọrun? ni gbigbọ́, ẹ gbọ́ t'emi, ki ẹ si jẹ eyi ti o dara, si jẹ ki inu nyin dùn ninu ọra.
Pín
Kà Isa 55Isa 55:2 Yoruba Bible (YCE)
Kí ló dé tí ẹ̀ ń ná owó yín lórí ohun tí kì í ṣe oúnjẹ? Tí ẹ sì ń ṣe làálàá lórí ohun tí kì í tẹ́ni lọ́rùn? Ẹ fetí sí ọ̀rọ̀ mi dáradára, kí ẹ sì jẹ ohun tí ó dára, ẹ jẹ oúnjẹ aládùn, kí inú yín ó dùn.
Pín
Kà Isa 55