Heb 13:16
Heb 13:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn ati mã ṣõre on ati mã pinfunni ẹ máṣe gbagbé: nitori irú ẹbọ wọnni ni inu Ọlọrun dùn si jọjọ.
Pín
Kà Heb 13Heb 13:16 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe rere, kí ẹ sì máa fún àwọn ẹlòmíràn ninu àwọn ohun ìní yín. Irú ẹbọ yìí ni inú Ọlọrun dùn sí.
Pín
Kà Heb 13