Heb 10:12-14
Heb 10:12-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn on, lẹhin igbati o ti ru ẹbọ kan fun ẹ̀ṣẹ titi lai, o joko li ọwọ́ ọtún Ọlọrun; Lati igbà na lọ, ó nreti titi a o fi fi awọn ọtá rẹ̀ ṣe apoti itisẹ rẹ̀. Nitori nipa ẹbọ kan o ti mu awọn ti a sọ di mimọ́ pé titi lai.
Pín
Kà Heb 10