Gẹn 4:25
Gẹn 4:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Adamu sì tún bá aya rẹ̀ lòpọ̀, ó sì bí ọmọkùnrin kan tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Seti, tí ó túmọ̀ sí pé, “Ọlọ́run fún mi ní ọmọkùnrin mìíràn ní ipò Abeli tí Kaini pa.”
Pín
Kà Gẹn 4Gẹn 4:25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Adamu si tun mọ̀ aya rẹ̀, o si bí ọmọkunrin kan, o si pè orukọ rẹ̀ ni Seti: o wipe, nitori Ọlọrun yàn irú-ọmọ miran fun mi ni ipò Abeli ti Kaini pa.
Pín
Kà Gẹn 4