Gal 6:9
Gal 6:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ má si jẹ ki agãra da wa ni rere iṣe: nitori awa ó ká nigbati akokò ba de, bi a kò bá ṣe ãrẹ̀.
Pín
Kà Gal 6Gal 6:9 Yoruba Bible (YCE)
Kí á má ṣe jẹ́ kí ó sú wa láti ṣe rere, nítorí nígbà tí ó bá yá, a óo kórè rẹ̀, bí a kò bá jẹ́ kí ó rẹ̀ wá.
Pín
Kà Gal 6