Gal 6:10
Gal 6:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Njẹ bi a ti nri akoko, ẹ jẹ ki a mã ṣore fun gbogbo enia, ati pãpa fun awọn ti iṣe ara ile igbagbọ́.
Pín
Kà Gal 6Gal 6:10 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí náà, bí a bá ti ń rí ààyè kí á máa ṣe oore fún gbogbo eniyan, pàápàá fún àwọn ìdílé onigbagbọ.
Pín
Kà Gal 6