Gal 5:14
Gal 5:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitoripe a kó gbogbo ofin já ninu ọ̀rọ kan, ani ninu eyi pe; Iwọ fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ.
Pín
Kà Gal 5Gal 5:14 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí gbolohun kan kó gbogbo òfin já, èyí ni pé “Fẹ́ràn ẹnìkejì rẹ bí ara rẹ.”
Pín
Kà Gal 5