Eks 33:13
Eks 33:13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Njẹ nisisiyi, emi bẹ̀ ọ, bi mo ba ri ore-ọfẹ li oju rẹ, fi ọ̀na rẹ hàn mi nisisiyi, ki emi ki o le mọ̀ ọ, ki emi ki o le ri ore-ọfẹ li oju rẹ: ki o si rò pe orilẹ-ède yi enia rẹ ni.
Pín
Kà Eks 33Eks 33:13 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Eks 33