Eks 31:12-13
Eks 31:12-13 Bibeli Mimọ (YBCV)
OLUWA si sọ fun Mose pe, Ki iwọ ki o sọ fun awọn ọmọ Israeli pe, Ọjọ́ isimi mi li ẹnyin o pamọ́ nitõtọ: nitori àmi ni lãrin emi ati lãrin nyin lati irandiran nyin; ki ẹnyin ki o le mọ̀ pe emi li OLUWA ti o yà nyin simimọ́.
Pín
Kà Eks 31