Efe 5:31-32
Efe 5:31-32 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori eyi li ọkunrin yio ṣe fi baba ati iya rẹ̀ silẹ, on o si dàpọ mọ́ aya rẹ̀, awọn mejeji a si di ara kan. Aṣiri nla li eyi: ṣugbọn emi nsọ nipa ti Kristi ati ti ijọ.
Pín
Kà Efe 5Nitori eyi li ọkunrin yio ṣe fi baba ati iya rẹ̀ silẹ, on o si dàpọ mọ́ aya rẹ̀, awọn mejeji a si di ara kan. Aṣiri nla li eyi: ṣugbọn emi nsọ nipa ti Kristi ati ti ijọ.