Nigbati iwọ ba si jẹun tán ti o si yo, nigbana ni iwọ o fi ibukún fun OLUWA Ọlọrun rẹ, nitori ilẹ rere na ti o fi fun ọ.
Nígbà tí ẹ bá jẹun, tí ẹ yó, ẹ óo dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA Ọlọrun yín fún ilẹ̀ dáradára tí ó fun yín.
Nígbà tí ẹ bá ti jẹ tí ẹ sì yó tán ẹ yin OLúWA Ọlọ́run yín fún pípèsè ilẹ̀ rere fún un yín.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò