Nitori OLUWA Ọlọrun rẹ ajonirun iná ni, Ọlọrun owú.
Nítorí iná tí ń jó ni run ni OLUWA Ọlọrun yín, Ọlọrun tíí máa ń jowú sì ni.
Torí pé iná ajónirun ni OLúWA Ọlọ́run yín, Ọlọ́run owú ni.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò