Ẹnyin kò gbọdọ bẹ̀ru wọn: nitoripe OLUWA Ọlọrun nyin, on ni yio jà fun nyin.
Ẹ kò gbọdọ̀ bẹ̀rù wọn rárá, nítorí pé OLUWA Ọlọrun yín ni ó ń jà fun yín.’
Ẹ má ṣe bẹ̀rù wọn, OLúWA Ọlọ́run yín tìkára rẹ̀ ni yóò jà fún un yín.”
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò