Dan 4:28-30
Dan 4:28-30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbogbo eyi de ba Nebukadnessari, ọba. Lẹhin oṣu mejila, o nrin kiri lori ãfin ijọba Babeli. Ọba si dahùn, o wipe, Ko ṣepe eyi ni Babeli nla, ti emi ti fi lile agbara mi kọ́ ni ile ijọba, ati fun ogo ọlanla mi?
Pín
Kà Dan 4