Iṣe Apo 9:15-16
Iṣe Apo 9:15-16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn Oluwa wi fun u pe, Mã lọ: nitori ohun elo àyo li on jẹ fun mi, lati gbe orukọ mi lọ si iwaju awọn Keferi, ati awọn ọba, ati awọn ọmọ Israeli: Nitori emi o fi gbogbo ìya ti kò le ṣaijẹ nitori orukọ mi han a.
Pín
Kà Iṣe Apo 9