Iṣe Apo 2:42-43
Iṣe Apo 2:42-43 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nwọn si duro ṣinṣin ninu ẹkọ́ awọn aposteli, ati ni idapọ, ni bibu akara ati ninu adura. Ẹ̀rù si ba gbogbo ọkàn: iṣẹ iyanu ati iṣẹ àmi pipọ li a ti ọwọ́ awọn aposteli ṣe.
Pín
Kà Iṣe Apo 2