Ṣugbọn ẹ mu akọrin kan fun mi wá nisisiyi. O si ṣe, nigbati akọrin na nkọrin, ọwọ Oluwa si bà le e.
Ó ní, “Ẹ pe akọrin kan wá.” Bí akọrin náà ti ń kọrin ni agbára OLUWA bà lé Eliṣa
Ṣùgbọ́n Nísinsin yìí mú wá fún mi ohun èlò orin olókùn.” Nígbà tí akọrin náà n kọrin, ọwọ́ OLúWA wá sórí Eliṣa.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò