II. Kor 9:14-15
II. Kor 9:14-15 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbati awọn tikarawọn pẹlu ẹ̀bẹ nitori nyin nṣafẹri nyin nitori ọpọ ore-ọfẹ Ọlọrun ti mbẹ ninu nyin. Ọpẹ́ ni fun Ọlọrun nitori alailesọ ẹ̀bun rẹ̀.
Pín
Kà II. Kor 9II. Kor 9:14-15 Yoruba Bible (YCE)
Wọn yóo wá máa gbadura fun yín, ọkàn wọn yóo fà sọ́dọ̀ yín nítorí ọ̀pọ̀ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun lórí yín. Ọpẹ́ ni fún Ọlọrun nítorí ẹ̀bùn rẹ̀ tí kò ní òǹkà.
Pín
Kà II. Kor 9