II. Kor 8:11
II. Kor 8:11 Yoruba Bible (YCE)
ó tó àkókò wàyí, ẹ ṣe é parí. Irú ìtara tí ẹ fẹ́ fi ṣe é ni kí ẹ fi parí rẹ̀. Kí ẹ ṣe é gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ní tó.
Pín
Kà II. Kor 8II. Kor 8:11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Njẹ nisisiyi ẹ pari ṣiṣe na pẹlu; bi imura-tẹlẹ ati ṣe ti wa, bẹni ki ipari si wa lati inu agbara nyin
Pín
Kà II. Kor 8