II. Kor 5:14
II. Kor 5:14 Yoruba Bible (YCE)
nítorí ìfẹ́ Kristi ni ó ń darí wa, nígbà tí a ti mọ̀ pé ẹnìkan ti kú fún gbogbo eniyan, a mọ̀ pé ikú gbogbo eniyan ni ó gbà kú.
Pín
Kà II. Kor 5II. Kor 5:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ifẹ Kristi nrọ̀ wa; nitori awa rò bayi, pe bi ẹnikan ba ti kú fun gbogbo enia, njẹ gbogbo wọn li o ti kú
Pín
Kà II. Kor 5