II. Kor 4:7
II. Kor 4:7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn awa ni iṣura yi ninu ohun èlo amọ̀, ki ọlá nla agbara na ki o le ṣe ti Ọlọrun, ki o má ti ọdọ wa wá.
Pín
Kà II. Kor 4II. Kor 4:7 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn bí ìkòkò amọ̀ ni àwa tí ìṣúra yìí wà ninu wa rí, kí ó lè hàn gbangba pé Ọlọrun ni ó ní agbára tí ó tóbi jùlọ, kì í ṣe àwa.
Pín
Kà II. Kor 4