II. Kor 11:24-25
II. Kor 11:24-25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigba marun ni mo gbà paṣan ogoji dín kan lọwọ awọn Ju. Nigba mẹta li a fi ọgọ lù mi, ẹkanṣoṣo li a sọ mi li okuta, ẹ̃mẹta li ọkọ̀ rì mi, ọsán kan ati oru kan ni mo wà ninu ibú.