I. Tes 5:18
I. Tes 5:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ mã dupẹ ninu ohun gbogbo: nitori eyi ni ifẹ Ọlọrun ninu Kristi Jesu fun nyin.
Pín
Kà I. Tes 5I. Tes 5:18 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ máa dúpẹ́ ninu ohun gbogbo nítorí èyí ni ìfẹ́ Ọlọrun nípa Kristi Jesu fun yín.
Pín
Kà I. Tes 5