I. Tes 5:11
I. Tes 5:11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitorina ẹ mã gbà ara nyin niyanju, ki ẹ si mã fi ẹsẹ ara nyin mulẹ, ani gẹgẹ bi ẹnyin ti nṣe.
Pín
Kà I. Tes 5I. Tes 5:11 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí náà, ẹ máa tu ara yín ninu, kí ẹ sì máa fún ara yín ní ìwúrí, bí ẹ ti ń ṣe.
Pín
Kà I. Tes 5