I. Pet 5:6-7
I. Pet 5:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitorina ẹ rẹ̀ ara nyin silẹ labẹ ọwọ́ agbara Ọlọrun, ki on ki o le gbé nyin ga li akokò. Ẹ mã kó gbogbo aniyan nyin le e; nitoriti on nṣe itọju nyin.
Pín
Kà I. Pet 5I. Pet 5:6-7 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí náà, ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ lábẹ́ ọwọ́ Ọlọrun tí ó lágbára, yóo gbe yín ga ní àkókò tí ó bá wọ̀. Ẹ kó gbogbo ìpayà yín tọ̀ ọ́ lọ, nítorí ìtọ́jú yín jẹ ẹ́ lógún.
Pín
Kà I. Pet 5