I. A. Ọba 10:24
I. A. Ọba 10:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbogbo aiye si nwá oju Solomoni, lati gbọ́ ọgbọ́n rẹ̀, ti Ọlọrun ti fi si i li ọkàn.
I. A. Ọba 10:24 Yoruba Bible (YCE)
Gbogbo aráyé a sì máa fẹ́ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, láti tẹ́tí sí ọgbọ́n tí Ọlọrun fún un.
I. A. Ọba 10:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbogbo aiye si nwá oju Solomoni, lati gbọ́ ọgbọ́n rẹ̀, ti Ọlọrun ti fi si i li ọkàn.