I. Joh 3:16
I. Joh 3:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nipa eyi li awa mọ̀ ifẹ nitoriti o fi ẹmí rẹ̀ lelẹ fun wa: o si yẹ ki awa fi ẹmí wa lelẹ fun awọn ará.
Pín
Kà I. Joh 3I. Joh 3:16 Yoruba Bible (YCE)
Ọ̀nà tí a fi mọ ìfẹ́ nìyí, pé ẹnìkan fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ fún wa. Nítorí náà, ó yẹ kí àwa náà fi ẹ̀mí wa lélẹ̀ fún àwọn ará.
Pín
Kà I. Joh 3