I. Kor 6:20
I. Kor 6:20 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori a ti rà nyin ni iye kan: nitorina ẹ yìn Ọlọrun logo ninu ara nyin, ati ninu ẹmí nyin, ti iṣe ti Ọlọrun.
Pín
Kà I. Kor 6I. Kor 6:20 Yoruba Bible (YCE)
Iyebíye ni Ọlọrun rà yín, nítorí náà, ẹ fi ara yín yin Ọlọrun.
Pín
Kà I. Kor 6