I. Kor 13:1
I. Kor 13:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
BI mo tilẹ nfọ oniruru ede ati ti angẹli, ti emi kò si ni ifẹ, emi dabi idẹ ti ndún, tabi bi kimbali olohùn goro.
Pín
Kà I. Kor 13I. Kor 13:1 Yoruba Bible (YCE)
Ǹ báà lè sọ oríṣìíríṣìí èdè tí eniyan ń fọ̀, kódà kí n tún lè sọ ti àwọn angẹli, bí n kò bá ní ìfẹ́, bí idẹ tí ń dún lásán ni mo rí; mo dàbí páànù tí wọn ń lù, tí ń hanni létí bí agogo.
Pín
Kà I. Kor 13