Wò o nisisiyi: nitori Oluwa ti yàn ọ lati kọ́ ile kan fun ibi mimọ́, mura le, ki iwọ si ṣe e.
Kíyèsára, nítorí pé OLUWA ti yàn ọ́ láti kọ́ ilé kan tí yóo jẹ́ ibi mímọ́, ṣe gírí, kí o sì kọ́ ọ.”
Gbèrò báyìí nítorí tí OLúWA ti yàn ọ́ láti kọ́ ilé OLúWA gẹ́gẹ́ bí ilé tí a yà sí mímọ́ fún OLúWA. Jẹ́ alágbára kí ó sì ṣe iṣẹ́ náà.”
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò