Saamu 86:9

Saamu 86:9 YCB

Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ dá yóò wá, láti wá jọ́sìn níwájú rẹ, OLúWA; wọn ó mú ògo wà fún orúkọ rẹ̀.