Èmi yóò máa fi ìbùkún fún OLúWA nígbà gbogbo; ìyìn rẹ̀ yóò máa wà ní ẹnu mi títí láé. Ọkàn mí yóò máa ṣògo nínú OLúWA; jẹ́ kí àwọn onírẹ̀lẹ̀ gbọ́ kí inú wọn kí ó sì máa dùn. Gbé OLúWA ga pẹ̀lú mi; kí ẹ sì jẹ́ kí a jọ gbé orúkọ rẹ̀ lékè. Èmi wá OLúWA, ó sì dá mi lóhùn; Ó sì gbà mí kúrò nínú ìbẹ̀rù mi gbogbo. Wọ́n wò ó, ìmọ́lẹ̀ sì mọ́ wọn; ojú kò sì tì wọ́n. Ọkùnrin olùpọ́njú yí kígbe, OLúWA sì gbóhùn rẹ̀; ó sì gbà á là kúrò nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀. Angẹli OLúWA yí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ ká ó sì gbà wọ́n.
Kà Saamu 34
Feti si Saamu 34
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 34:1-7
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò