Ohùn OLúWA ń ya bí ọwọ́ iná mọ̀nà Ohùn OLúWA ń mi aginjù. OLúWA mi aginjù Kadeṣi. Ohùn OLúWA ní ó lọ igi óákù, ó n mú abo àgbọ̀nrín bí, ó sì bọ́ igi igbó sí ìhòhò. Àti nínú tẹmpili rẹ̀ gbogbo ohùn wí pé “Ògo!”
Kà Saamu 29
Feti si Saamu 29
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 29:7-9
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò